Nọ́ḿbà 33:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Kénánì, ọba Árádì, tí ń gbé ìhà gúṣù ní ilẹ̀ Kénánì gbọ́ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń bọ̀.

Nọ́ḿbà 33

Nọ́ḿbà 33:32-48