Nọ́ḿbà 33:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí wọ́n sì ń sin gbogbo àkọ́bí wọn, ẹni tí Olúwa ti gbé lulẹ̀ láàrin wọn; nítorí tí Olúwa ti mú ẹ̀san wá sórí àwọn òrìṣà wọn.

Nọ́ḿbà 33

Nọ́ḿbà 33:1-9