21. Wọ́n kúrò ní Líbínà wọ́n sì pàgọ́ ní Rísà.
22. Wọ́n kúrò ní Rísà wọ́n sì pàgọ́ ní Kehelátà.
23. Wọ́n kúrò ní Kehelátà wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Ṣéférì.
24. Wọ́n kúrò lórí òkè Ṣéférì wọ́n sì págọ́ ní Hárádà.
25. Wọ́n kúrò ní Hárádà wọ́n sì pàgọ́ ní Mákélótì.
26. Wọ́n kúrò ní Mákélótì wọ́n sì pàgọ́ ní Táhátì.
27. Wọ́n kúrò ní Táhátì wọ́n sì pàgọ́ ní Térà.
28. Wọ́n kúrò ní Térà wọ́n sì pàgọ́ ní Mítíkà.
29. Wọ́n kúrò ní Mítíkà wọ́n pàgọ́ ní Hásímónà.
30. Wọ́n kúrò ní Hásímónà wọ́n sì pàgọ́ ní Mósérótù.