Nọ́ḿbà 33:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì kọ̀wé ìjáde lọ wọn ní ẹsẹẹsẹ gẹ́gẹ́ bí ìrìnàjò wọn, nípa àṣẹ Olúwa; Wọ̀nyí sì ni ìrìnàjò wọn gẹ́gẹ́ bí ìjáde lọ wọn.

Nọ́ḿbà 33

Nọ́ḿbà 33:1-11