Nọ́ḿbà 33:19-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Wọ́n kúrò ní Rítímà wọ́n sì pàgọ́ ní Rímónì-Pérésì.

20. Wọ́n kúrò ní Rímóni Pérésì wọ́n sì pàgọ́ ní Líbínà.

21. Wọ́n kúrò ní Líbínà wọ́n sì pàgọ́ ní Rísà.

22. Wọ́n kúrò ní Rísà wọ́n sì pàgọ́ ní Kehelátà.

23. Wọ́n kúrò ní Kehelátà wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Ṣéférì.

24. Wọ́n kúrò lórí òkè Ṣéférì wọ́n sì págọ́ ní Hárádà.

Nọ́ḿbà 33