16. Wọ́n kúrò ní ihà Ṣínáì wọ́n sì pàgọ́ ní Kabirotu-Hátafà.
17. Wọ́n kúrò ní Kabirotu-Hátafà wọ́n sì pàgọ́ ní Hásérótì.
18. Wọ́n kúrò ní Hásérótì wọ́n sì pàgọ́ ní Rítímà.
19. Wọ́n kúrò ní Rítímà wọ́n sì pàgọ́ ní Rímónì-Pérésì.
20. Wọ́n kúrò ní Rímóni Pérésì wọ́n sì pàgọ́ ní Líbínà.
21. Wọ́n kúrò ní Líbínà wọ́n sì pàgọ́ ní Rísà.
22. Wọ́n kúrò ní Rísà wọ́n sì pàgọ́ ní Kehelátà.