Nọ́ḿbà 33:13-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Wọ́n kúrò ní Dófákà wọ́n sì pàgọ́ ní Álúṣì.

14. Wọ́n kúrò ní Álúṣì wọ́n sì pàgọ́ ní Réfídímù níbi tí kò sí omi fún àwọn ènìyàn náà láti mu.

15. Wọ́n kúrò ní Refídímù wọ́n sì pàgọ́ ní ihà Ṣínáì.

16. Wọ́n kúrò ní ihà Ṣínáì wọ́n sì pàgọ́ ní Kabirotu-Hátafà.

17. Wọ́n kúrò ní Kabirotu-Hátafà wọ́n sì pàgọ́ ní Hásérótì.

18. Wọ́n kúrò ní Hásérótì wọ́n sì pàgọ́ ní Rítímà.

19. Wọ́n kúrò ní Rítímà wọ́n sì pàgọ́ ní Rímónì-Pérésì.

20. Wọ́n kúrò ní Rímóni Pérésì wọ́n sì pàgọ́ ní Líbínà.

Nọ́ḿbà 33