Nọ́ḿbà 32:41-42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Jáírì, ọmọ Mánásè gba ibùjókòó wọn, ó sì pè wọ́n ní Háfótù Jáírì.

42. Nébà gbà Kénátì àti àwọn ìtẹ̀dó rẹ̀, ó sì pè é ní Nóbà lẹ́yìn orúkọ ara rẹ̀.

Nọ́ḿbà 32