Nọ́ḿbà 32:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí a ó sì fi ṣe ilẹ̀ náà níwájú Olúwa; ẹ̀yin lè padà tí yóò sì di òmìnira lọ́wọ́ ìdè níwájú Olúwa àti Ísírẹ́lì. Ilẹ̀ yìí yóò sì jẹ́ ti yín níwájú Olúwa.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:12-26