Nọ́ḿbà 32:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú Olúwa ru sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó sì mú wọn rìn ní ihà fún ogójì (40) ọdún, títí tí àwọn ìran tí wọ́n ṣe búburú ní ojú rẹ̀ fi lọ.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:5-16