Nọ́ḿbà 31:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú àwọn olórí tí ó wà lórí ẹgbẹẹgbẹ̀rin ogun náà, àti àwọn balógun ọrọọrún wá sọ́dọ̀ Mósè.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:44-54