Nọ́ḿbà 31:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè fi ìdá náà fún Élíásárì, àlùfáà gẹ́gẹ́ bí ìdá ti Olúwa, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mósè.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:38-43