Nọ́ḿbà 31:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbẹ̀san lára àwọn Mídíánì fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn ìgbà náà a ó kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ.”

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:1-10