Nọ́ḿbà 30:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ọkọ rẹ̀ sì gbọ́ nípa èyí ṣùgbọ́n tí kò sọ nǹkan kan, nígbà náà ni ẹ̀jẹ́ tàbí ìdè tí ó fi de ara rẹ̀ tó dúró.

Nọ́ḿbà 30

Nọ́ḿbà 30:3-14