Nọ́ḿbà 3:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Owó tí a fi ra àwọn àkọ́bí ọmọ Ísírẹ́lì tó lé yìí, ni kí o kó fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀.

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:43-51