Nọ́ḿbà 29:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àti ní ọjọ́ keje, pèsè akọ màlúù méje, àgbò méjì, àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn mẹ́rìnlá ti ọlọ́dún kan, tí gbogbo rẹ̀ kò sì ní àbùkù.

Nọ́ḿbà 29

Nọ́ḿbà 29:23-40