Nọ́ḿbà 29:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti akọ màlúù, àgbò àti àgùntàn, pèsè ẹbọ jíjẹ àti ẹbọ mímu gẹ́gẹ́ bí iye wọn, gẹ́gẹ́ bí ìlànà.

Nọ́ḿbà 29

Nọ́ḿbà 29:14-25