Nọ́ḿbà 28:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ṣe eléyí papọ̀ ní àfikún ẹbọ ohun mímu yín àti ẹbọ ohun jíjẹ yín. Kí ẹ sì ri dájú pé àwọn ẹranko náà jẹ́ aláìlábùkù.

Nọ́ḿbà 28

Nọ́ḿbà 28:29-31