Nọ́ḿbà 28:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ní kí ẹ ṣe se oúnjẹ fún ẹbọ tí a fi iná ṣe ní ojojúmọ́ fún ọjọ́ méje gẹ́gẹ́ bí olóòrùn dídùn sí Olúwa; ó gbọdọ̀ jẹ́ èyí tí a fi iná ṣe ní àfikún ẹbọ ohun jíjẹ àti ohun mímu.

Nọ́ḿbà 28

Nọ́ḿbà 28:16-30