Nọ́ḿbà 28:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀dọ́ àgùntàn, ni kí ẹ rú ẹbọ ìyẹ̀fun ìyẹ̀fun kíkúnná tí a pò pọ̀ mọ́ òróró. Èyí ni ẹbọ sísun, òórùn dídùn, àti ẹbọ tí a ṣe fún Olúwa pẹ̀lú iná.

Nọ́ḿbà 28

Nọ́ḿbà 28:5-16