Nọ́ḿbà 27:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun tí àwọn ọmọbìnrin Ṣélófénátì ń sọ tọ̀nà. Ó gbọdọ̀ fún wọn ní ogún ìní ti baba wọn.

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:1-8