Nọ́ḿbà 27:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n súnmọ́ ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Ìpàdé wọ́n sì dúró níwájú Mósè, àti Élíásérì àlùfáà, àti níwájú àwọn olórí àti ìjọ, wọ́n sì wí pé,

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:1-3