Nọ́ḿbà 27:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbá náà Olúwa sọ fún Mósè pé, “Lọ sì orí òkè Ábárímù yìí, kí o sì lọ wo ilẹ̀ tí mo fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:6-13