Nọ́ḿbà 26:59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ aya Ámírámù sì ń jẹ́ Jókébédì, ọmọbìnrin Léfì, tí ìyá rẹ̀ bí fún Léfì ní Éjíbítì. Òun sì bí Árónì, Mósè, àti Míríámù arábìnrin wọn fún Ámírámù.

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:57-65