Nọ́ḿbà 26:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti àwọn ọmọ Náfítalì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:ti Jásélì, ìdílé àwọn ọmọ Jásélì:ti Gúnì, ìdílé àwọn ọmọ Gúnì;

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:39-53