Nọ́ḿbà 26:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti àwọn ọmọ Ásérì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:ti Ímínà, ìdílé àwọn ọmọ Ímínà;ti Íṣífì, ìdílé àwọn ọmọ Íṣífì;ti Béríà, ìdílé àwọn ọmọ Béríà;

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:34-54