Nọ́ḿbà 26:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Bẹ́là ní pasẹ̀ Árídì àti Náámánì nì yí:ti Árádì, ìdílé àwọn ọmọ Árádì;ti Náámánì, ìdílé àwọn ọmọ Náámánì.

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:37-45