Nọ́ḿbà 26:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn nì yí:tí Bẹ́là, ìdílé àwọn ọmọ Bẹ́là;ti Ásíbérì, ìdílé àwọn ọmọ Ásíbérì;ti Áhírámù, ìdílé àwọn ọmọ Áhírámù;

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:28-43