Nọ́ḿbà 26:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Mánásè:ti Mákírì, ìdílé Mákírì (Mákírì sì bí Gílíádì);ti Gílíádì, ìdílé àwọn ọmọ Gílíádì.

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:22-30