Nọ́ḿbà 25:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Ísírẹ́lì ṣe darapọ̀ mọ́ wọn tí wọ́n sì jọ ń sin Báálì ti Péórì. Ìbínú Olúwa sì ru sí wọn.

Nọ́ḿbà 25

Nọ́ḿbà 25:1-11