Nọ́ḿbà 25:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí pé wọ́n ṣe sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀ta nígbà tí wọ́n tàn yín nípa ìṣẹ̀lẹ̀ Péórì, àti arábìnrin wọn Kósíbì ọmọbìnrin ìjòyè Mídíánì kan, obìnrin tí a pa nígbà tí àjàkálẹ̀-àrùn ṣẹlẹ̀ nítorí Péórì.

Nọ́ḿbà 25

Nọ́ḿbà 25:9-18