Nọ́ḿbà 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì bẹ̀rẹ̀ òwe rẹ̀:“Ó wí pé Bálámù ọmọ Béórì,òwe ẹni tí ojú rẹ̀ mọ́lẹ̀,

Nọ́ḿbà 24

Nọ́ḿbà 24:1-8