Nọ́ḿbà 24:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Kó dà bí Bálákì bá fún mi ní ààfin rẹ̀ tí ó kún fún fàdákà àti wúrà, n kò le ṣe ohunkóhun lọ́wọ́ ara mi, yálà búburú tàbí rere, láti kọjá òfin Olúwa: ohun tí Olúwa bá wí ni èmi ó sọ’?

Nọ́ḿbà 24

Nọ́ḿbà 24:5-23