Nọ́ḿbà 23:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálámù sọ pé, “Kọ́ pẹpẹ méje fún mi níbí kí o sì pèsè akọ màlúù àti àgbò fún mi.”

Nọ́ḿbà 23

Nọ́ḿbà 23:27-30