Nọ́ḿbà 22:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálákì rú ẹbọ akọ màlúù pẹ̀lú àgùntàn, ó sì fún Bálámù ní díẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìjòyè tí ó wà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:34-41