Nọ́ḿbà 22:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálákì sì sọ fún Bálámù pé, “Ǹjẹ́ èmi kò a ránṣẹ́ kánjúkánjú sí ọ? Kí ló dé tí ìwọ kò fi wá sí ọ̀dọ̀ mi? Ṣé èmi kò tó láti sọ ọ́ di ẹni ńlá?”

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:32-40