Ańgẹ́lì Olúwa sọ fún Bálámù pé, “Lọ pẹ̀lú àwọn arákùnrin náà, ṣùgbọ́n nǹkan tí mo sọ fún ọ nìkan ni kí o sọ.” Nígbà náà Bálámù lọ pẹ̀lú àwọn ìjòyè Bálákì.