Nọ́ḿbà 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹ̀rù sì ba Móábù nítorí pé ọ̀pọ̀ ènìyàn wà níbẹ̀ nítòótọ́, Móábù kún fún ẹ̀rù nítorí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:1-4