Nọ́ḿbà 22:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní alẹ́ ọjọ́ náà Ọlọ́run sì tọ Bálámù wá ó sì sọ wí pé, “Nígbà tí ọkùnrin yìí ti wá pè ọ́, lọ pẹ̀lú wọn, ṣùgbọ́n ẹnu nǹkan tí mo sọ fún ọ ni kí o ṣe.”

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:14-22