Nọ́ḿbà 21:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ní fún ọ, ìwọ Móábù!Ẹ ti parun, ẹ̀yin ènìyàn Kémósì!Ó ti fi ọmọ rẹ̀ ọkùnrin sílẹ̀ gẹ́gẹ́bí ìṣẹ̀san àti ọmọ rẹ̀ obìnringẹ́gẹ bí ìgbékùn fún Ṣíhónì ọba àwọn Ámórì.

Nọ́ḿbà 21

Nọ́ḿbà 21:23-30