Nọ́ḿbà 20:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú ọ̀pá, náà kí o sì pe ìjọ àwọn ènìyàn jọ, ìwọ àti Árónì arákùnrin rẹ, kí ẹ sọ̀rọ̀ sí àpáta náà ní ójú wọn, yóò sì tú omi rẹ̀ jáde ìwọ ó sì fún ìjọ àti ẹran wọn mu”

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:1-15