Nọ́ḿbà 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni ó dé tí o fi mú wa gòkè kúrò ní Éjíbítì wá sí ibi búburú yìí? Ibi tí kò ní oúnjẹ tàbí igi ọ̀pọ̀tọ́, èṣo àjàrà tàbí pamonganati. Bẹ́ẹ̀ ni kò sí omi tí a ó mu níhín-ín!”

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:2-13