Nọ́ḿbà 20:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí gbogbo ìjọ ènìyàn sì gbọ́ pé Árónì ti kú, gbogbo ilé Ísírẹ́lì ṣe ìdárò rẹ̀ fún ọgbọ̀n (30) ọjọ́.

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:24-29