Nọ́ḿbà 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn bàbá ńlá wa sọ̀kalẹ̀ wá sí Éjíbítì, a sì gbé ibẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ọdún. Àwọn ará Éjíbítì ni wá lára àti àwọn bàbá wa,

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:5-24