Nọ́ḿbà 20:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì ránṣẹ́ láti Kádésì sí ọba Édómù, wí pé:“Èyí ni nǹkan tí arákùnrin rẹ Ísírẹ́lì sọ: Ìwọ ti mọ̀ nípa gbogbo ìnira, tí ó wá sí orí wa.

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:7-19