Nọ́ḿbà 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní osù kìn-ní-ní, gbogbo àgbájọ ọmọ Ísírẹ́lì gúnlẹ̀ sí pápá Sínì, wọ́n sì dúró ní Kádésì. Níbẹ̀ ni Míríámù kú, wọ́n sì sin ín.

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:1-7