Nọ́ḿbà 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yà Ásérì ni yóò pa ibùdó tẹ̀lé wọn. Olórí Ásérì ni Págíélì ọmọ Ókíránì.

Nọ́ḿbà 2

Nọ́ḿbà 2:26-34