Nọ́ḿbà 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìhà àríwá, ni ìpín Dánì yóò pa ibùdó sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olóri Dánì ni Áyésérì ọmọ Ámíṣádáyì.

Nọ́ḿbà 2

Nọ́ḿbà 2:20-32