Nọ́ḿbà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìhà gúsù ni ìpín ti Rúbẹ́nì pa ibùdó sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí Rúbẹ́nì ni Elisúrì ọmọ Ṣedúérì.

Nọ́ḿbà 2

Nọ́ḿbà 2:9-13