Nọ́ḿbà 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yẹ kí wọ́n darapọ̀ mọ́ ọ láti jẹ ìyà iṣẹ́ fún àìtọ́jú ibi ti Àgọ́ Ìpàdé àti gbogbo iṣẹ́ tí ó wà ní ibi àgọ́, àti wí pé kò sí ẹnikẹ́ni tí ó le wá sí ẹ̀gbẹ́ ibi tí o wà.

Nọ́ḿbà 18

Nọ́ḿbà 18:2-9